Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti doola ọkunrin mẹta to jẹ ọmọ orilẹede India ti awọn agbebọn kan ji gbe lọju ọna marosẹ Sagamu si Benin. Iroyin ni agbegbe Kajola ni awọn ajinigbe naa ti kọkọ ṣina ibọn bo ...